Halleluyah Ogo ni Fun Baba – Compiled, Arranged and Directed by Dr. Kunle Pinmiloye (K-Sticks) PhD.

Faith Score0
Faith Score0

Halleluyah Ogo ni Fun Baba – Ẹ Jẹ ka jumọ f’ọpẹ f’Ọlorun

Ẹ Jẹ ka jumọ f’ọpẹ f’Ọlorun
Orin iyin, at’ọpẹ lo yẹ wa
Iyanu n’ifẹ Rẹ si gbogbo wa
Ẹ kọrin ‘yin s’ Ọba Olore wa

Chorus:
Halleluyah! Ogo ni fun Baba
A f’ijo ilu yin Ọlọrun wa
Alaye ni o yin Ọ bo ti yẹ
Halleluyah! Ogo ni fun Baba

Ki l’a fi san j’awọn t’iku ti pa?
Iwọ lo f’ọwọ wọ wa di oni
‘Wọ lo n sọ wa to n gba wa lọw’ewu
Ẹ kọrin ‘yin s’Olutọju wa

Ohun wa ko dun to lati kọrin
Ẹnu wa ko gboro to fun ọpẹ
B’awa n’ẹgbẹrun ahọn nikọkan
Wọn kere ju lati gb’ọla Rẹ ga

Let us give thanks to God together
Songs of praises and thanks are befitting
Marvelous is Your love to all of us
Oh sing praises to our Gracious King

Chorus:
Hallelujah! Glory to the Father
We praise our God with dances and drums
Only the living will praise you properly
Hallelujah! Glory to the Father

How are we better than those who are no more?
It is you that have kept us till today
You keep us and You save us from evil
Sing praises to our Benefactor

Our voices are not sweet enough to sing
Our mouths are’nt wide enough to give You thanks
Even if we all have a thousand tongues each
They are too small to exalt Your honour.

 

Arranged and directed by Dr. Kunle Pinmiloye (K-sticks PhD.) and performed by Daystar Healing Streams of God during the 2015 Christmas.

Halleluyah Ogo ni Fun Baba – Compiled, Arranged and Directed by Dr. Kunle Pinmiloye (K-Sticks) PhD.

 

Estimated reading time: 2 minutes

We will be happy to hear your thoughts

      Leave a reply

      About Us

      Part of the Christianmedias organization, we are dedicated to sharing worship music to inspire prayer and devotion worldwide.

      World Tamil Christians - The Ultimate Collection of Christian Song Lyrics
      Logo